Jòhánù 7:23 BMY

23 Bí ènìyàn bá ń gba ìkọlà ní ọjọ́ ìsinmi, kí a má ba à rú òfin Mósè, ẹ ha ti ṣe ń bínú sími, nítorí mo mú ènìyàn kan láradá ṣáṣá ní ọjọ́ ìsinmi?

Ka pipe ipin Jòhánù 7

Wo Jòhánù 7:23 ni o tọ