Jòhánù 7:32 BMY

32 Àwọn Farisí gbọ́ pé, ìjọ ènìyàn ń sọ nǹkan wọ̀nyí lábẹ́lẹ̀ nípa rẹ̀; àwọn Farisí àti àwọn olórí àlùfáà sì rán àwọn onísẹ́ lọ láti mú un.

Ka pipe ipin Jòhánù 7

Wo Jòhánù 7:32 ni o tọ