Jòhánù 7:52 BMY

52 Wọ́n dáhùn wọ́n sì wí fún un pé, “Ìwọ pẹ̀lú wá láti Gálílì bí? Wá kiri, kí o sì wò nítorí kò sí wòlíì kan tí ó ti Gálílì dìde.”

Ka pipe ipin Jòhánù 7

Wo Jòhánù 7:52 ni o tọ