Jòhánù 8:11 BMY

11 Ó wí pé, “Kò sí ẹnìkan, Olúwa.”Jésù wí fún un pé, “Bẹ́ẹ̀ ni èmi náà kò dá ọ lẹ́bi: má a lọ, láti ìgbà yìí lọ, má dẹ́sẹ̀ mọ́.”

Ka pipe ipin Jòhánù 8

Wo Jòhánù 8:11 ni o tọ