Jòhánù 9:17 BMY

17 Nítorí náà, wọ́n sì tún wí fún afọ́jú náà pé, “Kí ni ìwọ wí nítorí rẹ̀, nítorí tí ó là ọ́ lójú?”Ó sì wí pé, “Wòlíì ní í ṣe.”

Ka pipe ipin Jòhánù 9

Wo Jòhánù 9:17 ni o tọ