Róòmù 11:11 BMY

11 Ǹjẹ́ èyí fi hàn wí pé: Ọlọ́run àwọn Júù rẹ ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀ láéláé? Rárá o. Ṣe ni Ọlọ́run ń fi ìgbàlà fún àwọn aláìkọlà. Nípa síṣe bẹ́ẹ̀ yóò mú kí àwọn Júù jowú, kí wọn sì béèrè ìgbàlà Ọlọ́run náà fún ara wọn.

Ka pipe ipin Róòmù 11

Wo Róòmù 11:11 ni o tọ