Róòmù 12:19 BMY

19 Olùfẹ́, ẹ má ṣe gbẹ̀san ara yín, ṣùgbọ́n ẹ fi ààyè sílẹ̀ fún ìbínú; nítorí a ti kọ ọ́ pé, Olúwa wí pé, “Èmi ni ẹ̀san, èmi ó gbẹ̀san.”

Ka pipe ipin Róòmù 12

Wo Róòmù 12:19 ni o tọ