Róòmù 12:20 BMY

20 Ṣùgbọ́n bí ebi bá ń pa ọ̀ta rẹ:“Fún un ní oúnjẹ; bí oùngbẹ bá ń gbẹ ẹ́,fún un ní omi mu;ní ṣíṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ ó kó ẹ̀yín iná lé e ní orí.”

Ka pipe ipin Róòmù 12

Wo Róòmù 12:20 ni o tọ