Róòmù 13:5 BMY

5 Nítorí náà, ó ṣe pàtàkì láti tẹríba fún àwọn alásẹ, kì í ṣe nítorí ìjìyà tó lé wáyé nìkan, ṣùgbọ́n nítorí ẹ̀rí-ọkàn pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Róòmù 13

Wo Róòmù 13:5 ni o tọ