Róòmù 13:6 BMY

6 San owó orí rẹ pẹ̀lú nítorí ìdí méjì pàtàkì tí a ti sọ wọ̀nyí. Nítorí pé ó se dandan kí a san owó oṣù fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba. Èyí yóò mú kí wọn tẹ̀ṣíwájú nínú iṣẹ́ Ọlọ́run náà. Wọn yóò sì máa tọ́jú yín.

Ka pipe ipin Róòmù 13

Wo Róòmù 13:6 ni o tọ