Róòmù 8:5 BMY

5 Àwọn tí ń ṣe gẹ́gẹ́ bí ohun ti ara, wọn a máa ronú ohun ti ara; ṣùgbọ́n àwọn ti ń e gẹ́gẹ́ bí ohun ti Ẹ̀mí, wọn a máa ronú ohun ti Ẹ̀mí.

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:5 ni o tọ