Róòmù 8:6 BMY

6 Ṣíṣe ìgbọ́ran sí ẹ̀mí Mímọ́ ń yọrí sí ìyè àti àlàáfíà. Ṣùgbọ́n títẹ̀lé ara ẹ̀ṣẹ̀ àtijọ́ náà ń yọrí sí ikú.

Ka pipe ipin Róòmù 8

Wo Róòmù 8:6 ni o tọ