Róòmù 9:6 BMY

6 Ṣùgbọ́n kì í ṣe pé ọ̀rọ̀ Ọlọ́run di asán. Kì í sá íṣe gbogbo àwọn tí ó ti inú Ísírẹ́lì wá, àwọn ni Ísírẹ́lì:

Ka pipe ipin Róòmù 9

Wo Róòmù 9:6 ni o tọ