Róòmù 9:7 BMY

7 Bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe pé, nítorí wọ́n jẹ́ irú ọmọ Ábúrámù, gbogbo wọn nii ọmọ: “Ṣùgbọ́n, nínú Ísákì li a ó ti pe irú ọmọ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Róòmù 9

Wo Róòmù 9:7 ni o tọ