Lefitiku 1:16 BM

16 kí ó fa àjẹsí rẹ̀ yọ, kí ó sì tu ìyẹ́ rẹ̀, kí ó dà á sí apá ìhà ìlà oòrùn pẹpẹ náà, níbi tí wọn ń da eérú sí.

Ka pipe ipin Lefitiku 1

Wo Lefitiku 1:16 ni o tọ