Lefitiku 10:13 BM

13 Ibi mímọ́ ni kí ẹ ti jẹ ẹ́, nítorí pé òun ni ìpín yín ati ti àwọn ọmọ yín, ninu ẹbọ sísun OLUWA, nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni OLUWA pa á láṣẹ fún mi.

Ka pipe ipin Lefitiku 10

Wo Lefitiku 10:13 ni o tọ