Lefitiku 11:10 BM

10 Ṣugbọn ohunkohun tí ó ń gbé inú òkun, tabi inú odò, ninu gbogbo àwọn ẹ̀dá alààyè tí wọn ń káàkiri inú omi, èyíkéyìí tí kò bá ní lẹbẹ ati ìpẹ́, ohun ìríra ni fun yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:10 ni o tọ