Lefitiku 11:36 BM

36 Tí ó bá jẹ́ odò, tabi kànga tí ó ní omi ni, wọn kì í ṣe aláìmọ́, ṣugbọn gbogbo nǹkan yòókù tí ó fara kan òkú wọn di aláìmọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:36 ni o tọ