Lefitiku 13:15 BM

15 Kí alufaa yẹ ojú egbò náà wò, kí ó sì pe abirùn náà ní aláìmọ́, irú egbò yìí jẹ́ aláìmọ́ nítorí pé ẹ̀tẹ̀ ni.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:15 ni o tọ