Lefitiku 13:28 BM

28 Bí ibi tí ó wú yìí bá wà bí ó ṣe wà, tí kò sì tàn káàkiri, ṣugbọn tí ó wòdú; àpá iná lásán ni, kí alufaa pè é ní mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:28 ni o tọ