Lefitiku 13:54 BM

54 alufaa yóo pàṣẹ pé kí wọ́n fọ ohun èlò tí àrùn wà lára rẹ̀ yìí, yóo sì tún tì í mọ́lé fún ọjọ́ meje sí i.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:54 ni o tọ