15 Alufaa yóo mú ninu ìwọ̀n ìgò òróró náà, yóo dà á sí àtẹ́lẹwọ́ òsì rẹ̀.
Ka pipe ipin Lefitiku 14
Wo Lefitiku 14:15 ni o tọ