Lefitiku 14:22 BM

22 ati àdàbà meji tabi ọmọ ẹyẹlé meji, èyíkéyìí tí apá rẹ̀ bá ká. Wọn yóo fi ọ̀kan rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, wọn yóo sì fi ekeji rú ẹbọ sísun.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:22 ni o tọ