Lefitiku 14:24 BM

24 Alufaa yóo mú àgbò ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀bi ati ìwọ̀n ìgò òróró náà, yóo fì wọ́n bí ẹbọ fífì níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:24 ni o tọ