Lefitiku 14:42 BM

42 Wọn yóo wá wá àwọn òkúta mìíràn, wọn yóo fi dípò àwọn tí wọ́n yọ kúrò, yóo sì fi ohun ìrẹ́lé mìíràn tún ilé náà rẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:42 ni o tọ