Lefitiku 15:21 BM

21 Kí ẹnikẹ́ni tí ó bá fara kan ibùsùn rẹ̀, fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀; yóo jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 15

Wo Lefitiku 15:21 ni o tọ