Lefitiku 15:28 BM

28 Ṣugbọn nígbà tí ẹ̀jẹ̀ náà bá dá, kí ó ka ọjọ́ meje lẹ́yìn ọjọ́ náà; lẹ́yìn náà, ó di mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 15

Wo Lefitiku 15:28 ni o tọ