Lefitiku 15:31 BM

31 “Bẹ́ẹ̀ ni o óo ṣe ya àwọn eniyan Israẹli kúrò lára àìmọ́ wọn, kí wọ́n má baà sọ ibi mímọ́ tí ó wà láàrin wọn di aláìmọ́, kí wọ́n sì kú.”

Ka pipe ipin Lefitiku 15

Wo Lefitiku 15:31 ni o tọ