Lefitiku 16:1 BM

1 Lẹ́yìn tí meji ninu àwọn ọmọ Aaroni kú, nígbà tí wọ́n fi iná tí kò mọ́ rúbọ sí OLUWA, OLUWA bá sọ fún Mose pé,

Ka pipe ipin Lefitiku 16

Wo Lefitiku 16:1 ni o tọ