Lefitiku 17:3 BM

3 Bí ẹnìkan ninu àwọn ọmọ Israẹli bá pa akọ mààlúù, tabi ọ̀dọ́ aguntan, tabi ewúrẹ́ kan ní ibùdó, tabi lẹ́yìn ibùdó,

Ka pipe ipin Lefitiku 17

Wo Lefitiku 17:3 ni o tọ