Lefitiku 18:18 BM

18 O kò gbọdọ̀ fi ọmọ ìyá, tabi ọmọ baba iyawo rẹ ṣe aya níwọ̀n ìgbà tí aya rẹ tí í ṣe ẹ̀gbọ́n rẹ̀ bá wà láàyè.

Ka pipe ipin Lefitiku 18

Wo Lefitiku 18:18 ni o tọ