Lefitiku 18:23 BM

23 O kò sì gbọdọ̀ bá ẹranko lòpọ̀, bẹ́ẹ̀ ni obinrin kò sì gbọdọ̀ fi ara rẹ̀ sílẹ̀ fún ẹranko láti bá a lòpọ̀; ìwà burúkú ni.

Ka pipe ipin Lefitiku 18

Wo Lefitiku 18:23 ni o tọ