Lefitiku 18:4 BM

4 Àwọn òfin mi ni ẹ gbọdọ̀ pamọ́, àwọn ìlànà mi sì ni ẹ gbọdọ̀ máa tẹ̀lé, tí ẹ sì gbọdọ̀ máa tọ̀. Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 18

Wo Lefitiku 18:4 ni o tọ