Lefitiku 18:7 BM

7 Ẹnikẹ́ni ninu yín kò gbọdọ̀ bá ìyá rẹ̀ lòpọ̀, nítorí pé, bí ẹni ń tú baba ẹni síhòòhò ni, ìyá rẹ ni, o kò gbọdọ̀ tú ìyá rẹ síhòòhò.

Ka pipe ipin Lefitiku 18

Wo Lefitiku 18:7 ni o tọ