Lefitiku 19:28 BM

28 Ẹ kò gbọdọ̀ ya ara yín lábẹ nítorí òkú, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ fín ara yín rárá. Èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:28 ni o tọ