3 Olukuluku yín gbọdọ̀ bọ̀wọ̀ fún ìyá ati baba rẹ̀, kí ó sì pa ọjọ́ ìsinmi mi mọ́. Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.
Ka pipe ipin Lefitiku 19
Wo Lefitiku 19:3 ni o tọ