Lefitiku 2:10 BM

10 Ohun tí ó bá ṣẹ́kù ninu ohun jíjẹ náà di ti Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀. Òun ni ó mọ́ jùlọ lára ẹbọ tí a fi iná sun sí OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:10 ni o tọ