Lefitiku 2:12 BM

12 O lè mú wọn wá fún OLUWA gẹ́gẹ́ bí ọrẹ àkọ́so oko, ṣugbọn wọn kò gbọdọ̀ fi wọ́n rúbọ lórí pẹpẹ bí ẹbọ olóòórùn dídùn.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:12 ni o tọ