Lefitiku 2:16 BM

16 Alufaa yóo bù ninu ọkà pípa ati òróró náà, pẹlu gbogbo turari orí rẹ̀, yóo sun ún gẹ́gẹ́ bí ẹbọ fún ìrántí. Ẹbọ sísun sí OLUWA ni.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:16 ni o tọ