Lefitiku 20:11 BM

11 Ẹnikẹ́ni tí ó bá bá aya baba rẹ̀ lòpọ̀, ó dójúti baba rẹ̀, pípa ni kí wọ́n pa àwọn mejeeji, ẹ̀jẹ̀ wọn yóo wà lórí ara wọn.

Ka pipe ipin Lefitiku 20

Wo Lefitiku 20:11 ni o tọ