Lefitiku 21:4 BM

4 Kò gbọdọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́, kí ó sì ba ara rẹ̀ jẹ́, nítorí olórí ló jẹ́ láàrin àwọn eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 21

Wo Lefitiku 21:4 ni o tọ