Lefitiku 22:29 BM

29 Nígbà tí ẹ bá sì ń rú ẹbọ ọpẹ́ sí OLUWA, ẹ gbọdọ̀ rú u ní ọ̀nà tí yóo fi jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà.

Ka pipe ipin Lefitiku 22

Wo Lefitiku 22:29 ni o tọ