Lefitiku 23:28 BM

28 Ẹ kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan ní ọjọ́ náà, nítorí ọjọ́ ètùtù ni, tí wọn yóo ṣe ètùtù fun yín níwájú OLUWA Ọlọrun yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:28 ni o tọ