Lefitiku 23:43 BM

43 kí àwọn arọmọdọmọ yín lè mọ̀ pé, inú àgọ́ ni mo mú kí àwọn ọmọ Israẹli máa gbé nígbà tí mo kó wọn jáde wá láti ilẹ̀ Ijipti. Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.”

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:43 ni o tọ