Lefitiku 24:4 BM

4 Aaroni yóo sì máa ṣe ìtọ́jú àwọn àtùpà tí wọ́n wà lórí ọ̀pá fìtílà wúrà, kí wọ́n lè máa wà ní títàn níwájú OLUWA nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Lefitiku 24

Wo Lefitiku 24:4 ni o tọ