Lefitiku 24:8 BM

8 Ní gbogbo ọjọ́ ìsinmi, Aaroni yóo máa tò wọ́n kalẹ̀ níwájú OLUWA nígbà gbogbo, ní orúkọ àwọn ọmọ Israẹli, gẹ́gẹ́ bíi majẹmu títí lae.

Ka pipe ipin Lefitiku 24

Wo Lefitiku 24:8 ni o tọ