Lefitiku 25:12 BM

12 Nítorí pé, ọdún jubili ni yóo máa jẹ́ fun yín, yóo jẹ́ ọdún mímọ́ fun yín, ninu oko ni ẹ óo ti máa jẹ ohun tí ó bá so.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:12 ni o tọ