Lefitiku 25:36 BM

36 O kò gbọdọ̀ gba èlé lọ́wọ́ rẹ̀, ṣugbọn bẹ̀rù Ọlọrun rẹ, kí o sì jẹ́ kí arakunrin rẹ máa bá ọ gbé.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:36 ni o tọ