Lefitiku 25:54 BM

54 Bí ẹnikẹ́ni kò bá ra ẹni náà pada lọ́nà tí a ti là sílẹ̀ wọnyi, wọ́n gbọdọ̀ dá òun ati àwọn ọmọ rẹ̀ sílẹ̀ nígbà tí ó bá di ọdún jubili.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:54 ni o tọ