Lefitiku 25:9 BM

9 Nígbà tí ó bá di ọjọ́ kẹwaa oṣù keje tíí ṣe ọjọ́ ètùtù, ẹ óo rán ọkunrin kan kí ó lọ fọn fèrè jákèjádò gbogbo ilẹ̀ yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:9 ni o tọ